Gbemi wo lootun mo t′ewo
Iri ko se le mi oo
Gbemi wo lootun mo t'ewo
Iri ko se le mi oo
Imole ko tan lootun so na mi
Itura ko ba lemi la t′odo re
Oluwa tio ni emi mi
Gbemi wo lootun mo t'ewo
Iri ko se le mi o
Gbemi wo lootun mo t'ewo
Iri ko se lemi o
Gbemi wo lootun mo t′ewo
Iri ko se lemi o
Imole ko tan lootun si ona mi
Itura ko ba lemi la t′odo re
Gbemi wo lootun mo t'ewo
Iri ko se lemi o
Nigbati idanwo ba de
Oluwa a so mi
Ona ma n suu ni igbami
Nigbati ona mi ba suu oluwa oo
Agbaagba tan ni
Imole lati orun ko tan si ona mi ko ma tan ni gba gbogbo
Ilekun ma se di
Agbara laiye ati orun owo re lowa
Ko si elomi l′eyin re
Iwo Nikan ni
Iwo Nikan naa ni mo Fe
Sa ma to mi oo
Nigbati o re okan mi o
Iri se lemi oo