Soapy

Naira Marley

O t′ẹsẹ'le bọ
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l′everybodyẸni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
(Barawo, barawo, barawo)
(Mọ ba ṣa ni barawo)
O tẹsẹ'le bọ (O tẹsẹ'le bọ)
Yahoo ni babalawo (Yahoo ni babalawo)
Ole l′everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
O fẹ ṣe′ka fun mi (O fẹ ṣe'ka fun mi)
Mi o l′ogun mo ni Kurani (mo ni Kurani)
Mo dẹ n ṣ'adura mi
Bi m ṣe n ṣ′adura mi
Allah n gba'dura mi (Allah n gba′dura mi)
A ti lọ a ti de (A ti lọ a ti de)
Ẹni ori yọ o di'le (Ẹni ori yọ o di'le)
Ẹni ba lọ l′o ba de
Igba ti m pada de
N′ṣe l'ọn de mi l′ade (N'ṣe l′ọn de mi l'ade)
K′ade ko pẹ l'ori (K'ade ko pẹ l′ori)
Ki bata k′o pe l'ẹsẹ (Ki bata k′o pe l'ẹsẹ)
K′awọn ọta mi kan l'ẹsẹ
Inside life (Inside)
O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)
Inside life (Inside)
O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)
Inside life
Awọn kan n jẹ′ya
Awọn kan n chop life
(Inside life) Inside life
Awọn kan n ṣ'epe
Awọn kan n jẹ'wa
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy
T′o o ba ni′yawo n'le k′o jo soapy
(Soapy!) soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)
Soapy (Soapy)
Ab'ẹyin naa soapy? (Ab′ẹyin naa soapy?)
Soapy (Soapy)
Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo OMO t'o ba lọ n soapy (Soapy!)
Ṣ′o d'owo mọ? (Ṣ'o d′owo mọ?)
O wa sọ p′o o mọ Naira (O wa sọ p'o o mọ Naira)
O wuwo l′ọwọ
Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira (Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira)
Aja fẹ de'na d′ẹkun
Kekere ẹkun o ma n s'ẹgbẹ aja (ko n ṣ′ẹgbẹ aja)
Wọn n bẹ ni, Ma fọ
Awọn naa o fẹ wahala (Awọn naa o fẹ wahala)
I just wanna make Mama proud (I just wanna make Mama proud)
They want to make Mama cry
Mama you gonna cry no more
T'ẹ ba sun'kun gan ẹ o sọ′kun ayọ (ẹ o sọ′kun ayọ)
Ti m ba n jo k'ẹ ba m yọ (k′ẹ ba m yọ)
K'ọrọ mi ja s′ayọ (K'ọrọ mi ja s′ayọ)
Inside life, Inside life
Do a one course, it's my life (Ku'onbẹ!)
Inside life (Inside)
O ti ri 5 Alive (O ti ri 5 Alive)
Inside life (Inside)
O ti ri Deeper Life (O ti ri Deeper Life)
Inside life
Awọn kan n jẹ′ya
Awọn kan n chop life
(Inside life) Inside life
Awọn kan n ṣ′epe
Awọn kan n jẹ'wa
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy (Kirikiri n jo soapy)
Jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy (Ikoyi prison n jo soapy)
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy (wọn n jo soapy)
Jo soapy
T′o o ba ni'yawo n′le k'o jo soapy
(Soapy!) soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy (Bọda yi n jo soapy)
Soapy (Soapy)
Ab′ẹyin naa soapy? (Ab'ẹyin naa soapy?)
Soapy (Soapy)
Single father n jo soapy (Single father n jo soapy)
Soapy, ma lọ lo OMO t'o ba lọ n soapy
(Soapy!)