Beast & Peace

MohBad

(The winds will come)
(To steal the words I say) Imole
Ahn
Ahn, mó silent mood, but beast ní mí
Mo lé cause violence but still, peace ní mí
You don′t have to hurt me, before you win
You don't have to kill somebody before you sin
Óṣá lé browse, láì dè ló sub oh
Òde lé go far without God oh
So, mó dúró t′Olùwà
So, kò kín ṣe irú wá
Even tọbà fún yín làbọ pẹ'lú spoon, ẹ lè j'ojú wá

Èmi má dẹ tí bad, láti àyé la′dì-la′dì
Láti àyé 1990 tó ńlù beat pati-pati
Èmi tímo feel bad, mó dẹ tí feel good
Now, mó feel better, Surulere bí Ojuelegba
Torípé mó wọ ńkán, wọn sọ pé mowà on drug
Now, mowà on top, life mí òdẹ ní contour
Mó pàwọn ni Naija, ó tún báwọn ní London
Fún wọn ní KPK, Ponmo, Light boy, wo, mo ńta'na
(Light-boy, mo ńta′na)

Uh, mummy mí àti daddy mí, wọn kàn ló ń question mí
Wọn ní, "Ìbò l'otí rí vibe yi, ṣé ọwọ demon?"
Àwọn tọ senior mí, wọn bèrè, "Where you see money?"
Àwọn tí mó jùlọ, wọn photocopy mí
First cashout mí, ọmọ ìyá, mó dè fí rá bazooka
Mo kó fún àwọn sharp shooter
Ẹ má bínú tọbá dá sí′ta
Tra-ta-ta-ta-ta-ta fún àwọn fake nigga

Àwọn t'ofẹ shame mí
Wo, èmi wá shameless
Wọn fẹ stain white mí, but mo wá stainless
Àwọn nigga tọ leave mí, wọn lé rí realness
Torí pé silence mí, no mean say na weakness
Shoutout sí Iba J, Diarra, pẹ′lú Hayan
CY, Darosha, Prime Boy
Spending with my daddy, life mí wá splendid
Ológo, Zomo, TIA, Bella

(Chukwuchilly)
Soul
Mí ṣámọ
Wọn ní irú ẹ
Irú ẹ tóní, kò kíń ṣe original
(Boombah)
O fẹ, o fẹ sùn mó mí
But, kò kíń ṣe òun gan-gan