Grateful

Asa

Era ilẹ′, era ilẹ', wọn yìn Bàbá l′òkè
'Yanrìn, òkun, 'yanrìn, òkun, wọn yìn Bàbá l′òkè
Ẹranko ilé, ẹranko igbó, wọn yín Bàbá l′òkèÀwọn aláìní, àwọn tán tí ní, wọn yìn Bàbá l'òkè

Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe′yán
Kò tó mọ pé Bàbá ń bẹ l'òkè
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe′yán
Kò tó mọ pé loótọ' ò ńbẹ l′òkè

You don't have to wait 'til you feel the pain
You can start right now
It′s not too late
It′s not too late to be grateful!

Ah, ah, uhm
Ah, ah, ah, ah-ah, ah
Hmm-mmm

Era ilẹ', era ilẹ′, wọn yìn Bàbá l'òkè
′Yanrìn òkun, 'yanrìn òkun, wọn yìn Bàbá l′òkè
Pé mo wà láyé, mo wà láàyè
Gbogbo òun tí mò ní, má fí yìn ò lógo
Believe this world a better place
Ah-ah-ah, eh-eh

Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yàn
Kò tó mọ pé Bàbá ńbẹ l'òkè (okay)
Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe′yàn
Kò tó mọ pé loótọ′ ò ńbẹ l'òkè

You don′t have to wait 'til you feel the pain
You can start right now (okay)
It′s not too late (it's not too late)
It′s not too late to be grateful (yes)

Ahh
O rí bí mo ṣe ńf'ẹgbẹ yìn Bàbá

Ta, du-ba, du-ba (hey)
Ta, du-ba, du-bu (hey)
Ba, du-ba, du-ba (hey)
Da, du-da, du-bu (hey)

It's not too late
Uhh-uh-uh, eh (hey)
Ta, du-ba, du-bu
(Yeah-yeah, oh, that′s right)